Ìṣe Àwọn Aposteli 23:23 BM

23 Ọ̀gágun náà bá pe meji ninu àwọn balogun ọ̀rún tí ó wà lábẹ́ rẹ̀, ó ní, “Ẹ lọ mú igba ọmọ-ogun ati aadọrin ẹlẹ́ṣin ati igba ọmọ-ogun tí ó ní ọ̀kọ̀. Ẹ óo lọ sí Kesaria. Kí ẹ múra láti lọ ní agogo mẹsan-an alẹ́.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 23

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 23:23 ni o tọ