Ìṣe Àwọn Aposteli 23:27 BM

27 Àwọn Juu mú ọkunrin yìí, wọ́n fẹ́ pa á. Mo gbà á lọ́wọ́ wọn pẹlu àwọn ọmọ-ogun mi nítorí mo gbọ́ pé ọmọ-ìbílẹ̀ Romu ni.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 23

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 23:27 ni o tọ