Ìṣe Àwọn Aposteli 23:33 BM

33 Àwọn ọmọ-ogun ẹlẹ́ṣin bá a lọ sí Kesaria. Wọ́n fún gomina ní ìwé, wọ́n sì fa Paulu lé e lọ́wọ́.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 23

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 23:33 ni o tọ