1 Lẹ́yìn ọjọ́ marun-un, Anania olórí Alufaa dé pẹlu àwọn àgbààgbà ati agbẹjọ́rò kan tí ń jẹ́ Tatulu. Wọ́n ro ẹjọ́ Paulu fún gomina.
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 24
Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 24:1 ni o tọ