Ìṣe Àwọn Aposteli 24:15 BM

15 Mo sì ń wojú Ọlọrun nítorí pé mo ní ìrètí kan náà tí àwọn ará ibí yìí pàápàá tí wọn ń rojọ́ mi ní, pé gbogbo òkú ni yóo jinde, ati ẹni rere ati ẹni burúkú.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 24

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 24:15 ni o tọ