Ìṣe Àwọn Aposteli 24:26 BM

26 Sibẹ ó ń retí pé Paulu yóo fún òun ní owó. Nítorí náà, a máa ranṣẹ pè é lemọ́lemọ́ láti bá a sọ̀rọ̀.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 24

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 24:26 ni o tọ