Ìṣe Àwọn Aposteli 24:8 BM

8 Òun ni ó pàṣẹ pé kí àwọn tí wọ́n fi ẹ̀sùn kàn án wá siwaju yín.] Bí ẹ bá wádìí lẹ́nu òun fúnrarẹ̀, ẹ óo rí i pé òtítọ́ ni gbogbo ẹjọ́ rẹ̀ tí a fi sùn yín.”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 24

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 24:8 ni o tọ