12 Fẹstu forí-korí pẹlu àwọn olùbádámọ̀ràn rẹ̀, ó wá dáhùn pé, “O ti gbé ẹjọ́ rẹ lọ siwaju ọba Kesari; nítorí náà o gbọdọ̀ lọ sọ́dọ̀ ọba Kesari.”
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 25
Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 25:12 ni o tọ