Ìṣe Àwọn Aposteli 25:16 BM

16 Mo dá wọn lóhùn pé kì í ṣe àṣà àwọn ará Romu láti fa ẹnikẹ́ni lé àwọn olùfisùn rẹ̀ lọ́wọ́ láì fún un ní anfaani láti fojúkojú pẹlu wọn, kí ó sì sọ ti ẹnu rẹ̀ nípa ẹ̀sùn tí wọ́n fi kàn án.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 25

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 25:16 ni o tọ