Ìṣe Àwọn Aposteli 25:6 BM

6 Kò lò ju bí ọjọ́ mẹjọ tabi mẹ́wàá lọ pẹlu wọn, ni ó bá pada lọ sí Kesaria. Ní ọjọ́ keji ó jókòó ninu kóòtù, ó pàṣẹ pé kí wọ́n mú Paulu wá.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 25

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 25:6 ni o tọ