Ìṣe Àwọn Aposteli 25:9 BM

9 Nítorí pé Fẹstu ń wá ojurere àwọn Juu, ó bi Paulu pé, “Ṣé o óo kálọ sí Jerusalẹmu, kí n dá ẹjọ́ yìí níbẹ̀?”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 25

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 25:9 ni o tọ