Ìṣe Àwọn Aposteli 26:10 BM

10 Mo ṣe díẹ̀ ní Jerusalẹmu. Pupọ ninu àwọn onigbagbọ ni mo tì mọ́lé, lẹ́yìn tí mo ti gba àṣẹ lọ́wọ́ àwọn olórí alufaa. Wọn á máa pa wọ́n báyìí, èmi náà á sì ní bẹ́ẹ̀ gan-an ló yẹ wọ́n.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 26

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 26:10 ni o tọ