16 Dìde nàró. Ohun tí mo fi farahàn ọ́ nìyí: mo ti yàn ọ́ láti jẹ́ iranṣẹ mi, kí o lè jẹ́rìí ohun tí o rí, ati ohun tí n óo fihàn ọ́.
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 26
Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 26:16 ni o tọ