Ìṣe Àwọn Aposteli 27:1 BM

1 Nígbà tí wọ́n pinnu láti fi wá ranṣẹ sí Itali, wọ́n fi Paulu ati àwọn ẹlẹ́wọ̀n mìíràn lé balogun ọ̀rún kan tí ó ń jẹ́ Juliọsi lọ́wọ́, ó jẹ́ ọ̀gágun ti ẹgbẹ́ kan tí wọn ń pè ní Ọmọ-ogun Augustu.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 27

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 27:1 ni o tọ