Ìṣe Àwọn Aposteli 27:14 BM

14 Kò pẹ́ pupọ ni afẹ́fẹ́ líle kan láti erékùṣù náà bá bì lu ọkọ̀. Wọ́n ń pe afẹ́fẹ́ náà ní èyí tí ó wá láti àríwá ìlà oòrùn.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 27

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 27:14 ni o tọ