Ìṣe Àwọn Aposteli 27:21 BM

21 Lẹ́yìn tí wọ́n ti wà fún ọpọlọpọ ọjọ́, láì jẹun, Paulu dìde dúró láàrin wọn, ó ní, “Ẹ̀yin eniyan, ẹ̀ bá ti gbọ́ tèmi kí ẹ má ṣíkọ̀ ní Kirete. Irú ewu ati òfò yìí ìbá tí sí.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 27

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 27:21 ni o tọ