24 ‘Má bẹ̀rù, Paulu. Dandan ni kí o dé iwájú Kesari. Mo fẹ́ kí o mọ̀ pé Ọlọrun ti fi ẹ̀mí gbogbo àwọn ẹni tí ó wọkọ̀ pẹlu rẹ jíǹkí rẹ.’
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 27
Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 27:24 ni o tọ