Ìṣe Àwọn Aposteli 27:8 BM

8 Tipátipá ni a fi ń lọ lẹ́bàá èbúté títí a fi dé ibìkan tí wọn ń pè ní Èbúté-rere tí kò jìnnà sí ìlú Lasia.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 27

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 27:8 ni o tọ