Ìṣe Àwọn Aposteli 28:25 BM

25 Nígbà tí ohùn wọn kò dọ́gba láàrin ara wọn, wọ́n bá ń túká lọ. Paulu wá tún sọ gbolohun kan, ó ní, “Òtítọ́ ni Ẹ̀mí Mímọ́ sọ láti ẹnu wolii Aisaya sí àwọn baba-ńlá yín.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 28

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 28:25 ni o tọ