8 Ní àkókò yìí baba Pubiliusi ń ṣàìsàn: ibà ń ṣe é, ó sì ń ya ìgbẹ́-ọ̀rìn. Paulu bá wọ iyàrá tọ̀ ọ́ lọ. Lẹ́yìn tí ó gbadura, ó gbé ọwọ́ lé e, ó sì wò ó sàn.
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 28
Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 28:8 ni o tọ