Ìṣe Àwọn Aposteli 3:11 BM

11 Bí ọkunrin náà ti rọ̀ mọ́ Peteru ati Johanu, gbogbo àwọn eniyan sáré pẹlu ìyanu lọ sọ́dọ̀ wọn ní ọ̀dẹ̀dẹ̀ tí à ń pè ní ti Solomoni.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 3

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 3:11 ni o tọ