Ìṣe Àwọn Aposteli 3:13 BM

13 Ọlọrun Abrahamu, Ọlọrun Isaaki ati Ọlọrun Jakọbu, Ọlọrun àwọn baba wa ni ó dá Ọmọ rẹ̀, Jesu lọ́lá. Jesu yìí ni ẹ fi lé àwọn ọ̀tá lọ́wọ́, òun ni ẹ sẹ́ níwájú Pilatu nígbà tí ó fi dá a sílẹ̀.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 3

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 3:13 ni o tọ