25 Ẹ̀yin gan-an ni ọmọ àwọn wolii; nítorí tiyín ni Ọlọrun ṣe bá àwọn baba yín dá majẹmu, nígbà tí ó sọ fún Abrahamu pé, ‘Nípa ọmọ rẹ ni n óo ṣe bukun gbogbo orílẹ̀-èdè ayé.’
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 3
Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 3:25 ni o tọ