Ìṣe Àwọn Aposteli 3:6 BM

6 Peteru bá sọ fún un pé, “N kò ní fadaka tabi wúrà, ṣugbọn n óo fún ọ ní ohun tí mo ní. Ní orúkọ Jesu Kristi ti Nasarẹti, máa rìn.”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 3

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 3:6 ni o tọ