Ìṣe Àwọn Aposteli 4:17 BM

17 Ṣugbọn kí ó má baà tún máa tàn kálẹ̀ sí i láàrin àwọn eniyan, ẹ jẹ́ kí á kìlọ̀ fún wọn pé wọn kò gbọdọ̀ dárúkọ Jesu fún ẹnikẹ́ni mọ́.”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 4

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 4:17 ni o tọ