Ìṣe Àwọn Aposteli 4:19 BM

19 Ṣugbọn Peteru ati Johanu dá wọn lóhùn pé, “Èwo ni ó tọ́ níwájú Ọlọrun: kí á gbọ́ràn si yín lẹ́nu ni, tabi kí á gbọ́ràn sí Ọlọrun lẹ́nu? Ẹ̀yin náà ẹ dà á rò.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 4

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 4:19 ni o tọ