Ìṣe Àwọn Aposteli 4:24 BM

24 Nígbà tí wọ́n gbọ́, wọ́n jọ ké pe Ọlọrun pé, “Oluwa, ìwọ tí ó dá ọ̀run ati ayé ati òkun ati gbogbo ohun tí ó wà ninu wọn,

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 4

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 4:24 ni o tọ