Ìṣe Àwọn Aposteli 4:7 BM

7 Wọ́n mú Peteru ati Johanu wá siwaju ìgbìmọ̀. Wọ́n wá bi wọ́n pé, “Irú agbára wo ni ẹ fi ṣe ohun tí ẹ ṣe yìí? Orúkọ ta ni ẹ lò?”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 4

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 4:7 ni o tọ