Ìṣe Àwọn Aposteli 5:28 BM

28 “Mo ṣebí a pàṣẹ fun yín pé kí ẹ má fi orúkọ yìí kọ́ ẹnikẹ́ni mọ́? Sibẹ gbogbo ará Jerusalẹmu ni ó ti gbọ́ nípa ẹ̀kọ́ yín yìí. Ẹ wá tún di ẹ̀bi ẹ̀jẹ̀ ọkunrin yìí lé wa lórí?”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 5

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 5:28 ni o tọ