Ìṣe Àwọn Aposteli 6:5 BM

5 Ọ̀rọ̀ yìí dára lójú gbogbo àwùjọ, wọ́n bá yan Stefanu. Stefanu yìí jẹ́ onigbagbọ tọkàntọkàn, tí ó kún fún Ẹ̀mí Mímọ́. Wọ́n yan Filipi náà ati Prokoru ati Nikanọ ati Timoni ati Pamena ati Nikolausi ará Antioku tí ó ti gba ẹ̀sìn àwọn Juu.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 6

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 6:5 ni o tọ