8 Stefanu ń ṣe iṣẹ́ ìyanu ati iṣẹ́ abàmì ńlá láàrin àwọn eniyan nítorí pé ẹ̀bùn ati agbára Ọlọrun pọ̀ lọ́wọ́ rẹ̀.
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 6
Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 6:8 ni o tọ