Ìṣe Àwọn Aposteli 7:10 BM

10 Ọlọrun yọ ọ́ kúrò ninu gbogbo ìpọ́njú tí ó rí. Nígbà tí ó yọ siwaju Farao, ọba Ijipti, Ọlọrun fún un lọ́gbọ́n, ó sì jẹ́ kí ó rí ojú àánú ọba Ijipti. Farao bá fi jẹ gomina lórí gbogbo ilẹ̀ Ijipti ati lórí ààfin ọba.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 7

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 7:10 ni o tọ