Ìṣe Àwọn Aposteli 7:24 BM

24 Ó bá rí ọ̀kan ninu àwọn ará rẹ̀ tí ará Ijipti ń jẹ níyà. Ó bá lọ gbà á sílẹ̀. Ó gbẹ̀san ìyà tí wọ́n ti fi jẹ ẹ́, ó lu ará Ijipti náà pa.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 7

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 7:24 ni o tọ