Ìṣe Àwọn Aposteli 7:4 BM

4 Ó bá jáde kúrò ní ilẹ̀ Kalidea láti máa gbé Kenaani. Nígbà tí baba rẹ̀ kú, ó kúrò níbẹ̀ láti wá máa gbé ilẹ̀ yìí, níbi tí ẹ̀ ń gbé nisinsinyii.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 7

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 7:4 ni o tọ