42 Ọlọrun bá pada lẹ́yìn wọn, ó fi wọ́n sílẹ̀ láti máa sin ìràwọ̀ ojú ọ̀run, gẹ́gẹ́ bí ó ti wà ní àkọsílẹ̀ ninu ìwé àwọn wolii pé,‘Ẹ̀yin ọmọ Israẹli,ǹjẹ́ ẹ mú ẹran wá fi rúbọ sí mi fún ogoji ọdún ní aṣálẹ̀?
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 7
Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 7:42 ni o tọ