Ìṣe Àwọn Aposteli 7:52 BM

52 Èwo ninu àwọn wolii ni àwọn Baba yín kò ṣe inúnibíni sí? Wọ́n pa àwọn tí wọ́n sọtẹ́lẹ̀ pé Ẹni olódodo yóo dé. Ní àkókò yìí ẹ wá dìtẹ̀ sí i, ẹ ṣe ikú pa á.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 7

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 7:52 ni o tọ