6 Ọlọrun sọ fún un pé, ‘Àwọn ọmọ rẹ yóo jẹ́ àlejò ní ilẹ̀ àjèjì. Àwọn eniyan ibẹ̀ yóo lò wọ́n bí ẹrú, wọn óo pọ́n wọn lójú fún irinwo (400) ọdún.
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 7
Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 7:6 ni o tọ