Ìṣe Àwọn Aposteli 8:10 BM

10 Gbogbo eniyan ló kà á kún; ati àwọn eniyan yẹpẹrẹ ati àwọn eniyan pataki wọn. Wọ́n ní, “Eléyìí ní agbára Ọlọrun tí à ń pè ní ‘Agbára ńlá.’ ”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 8

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 8:10 ni o tọ