Ìṣe Àwọn Aposteli 8:13 BM

13 Simoni náà gbàgbọ́, ó ṣe ìrìbọmi, ni ó bá fara mọ́ Filipi. Nígbà tí ó rí iṣẹ́ abàmì ati iṣẹ́ ìyanu ńlá tí ó ń ṣe, ẹnu yà á.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 8

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 8:13 ni o tọ