Ìṣe Àwọn Aposteli 8:26 BM

26 Angẹli Oluwa sọ fún Filipi pé, “Dìde kí o lọ sí apá gúsù, ní ọ̀nà tí ó lọ láti Jerusalẹmu sí Gasa.” (Aṣálẹ̀ ni ọ̀nà yìí gbà lọ.)

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 8

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 8:26 ni o tọ