10 Ọmọ-ẹ̀yìn Jesu kan wà ní Damasku tí ń jẹ́ Anania. Oluwa pè é ní ojú ìran, ó ní, “Anania!”Anania bá dáhùn pé, “Èmi nìyí, Oluwa.”
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 9
Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 9:10 ni o tọ