Ìṣe Àwọn Aposteli 9:24 BM

24 Ṣugbọn Saulu gbọ́ nípa ète wọn. Wọ́n ń ṣọ́ àwọn ẹnu odi ìlú tọ̀sán-tòru kí wọ́n baà lè pa á.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 9

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 9:24 ni o tọ