40 Peteru bá ti gbogbo wọn jáde, ó kúnlẹ̀, ó gbadura. Ó bá kọjú sí òkú náà, ó ní, “Tabita, dìde.” Ni Tabita bá lajú, ó rí Peteru, ó bá dìde jókòó.
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 9
Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 9:40 ni o tọ