Ìfihàn 1:19 BM

19 Nítorí náà kọ àwọn ohun tí o rí sílẹ̀, ati àwọn ohun tí ó wà nisinsinyii ati àwọn ohun tí yóo ṣẹlẹ̀ lẹ́yìn ọ̀la.

Ka pipe ipin Ìfihàn 1

Wo Ìfihàn 1:19 ni o tọ