Ìfihàn 10:11 BM

11 Wọ́n bá sọ fún mi pé, “O níláti tún kéde fún ọ̀pọ̀ àwọn eniyan ati oríṣìíríṣìí ẹ̀yà ati àwọn orílẹ̀-èdè, ati ọpọlọpọ ìjọba.”

Ka pipe ipin Ìfihàn 10

Wo Ìfihàn 10:11 ni o tọ