Ìfihàn 11:13 BM

13 Ilẹ̀ mì tìtì, ìdámẹ́wàá ìlú bá wó. Ẹẹdẹgbaarin (7,000) eniyan ni ó kú nígbà tí ilẹ̀ náà mì. Ẹ̀rù ba àwọn tí ó kù, wọ́n sì fi ògo fún Ọlọrun ọ̀run.

Ka pipe ipin Ìfihàn 11

Wo Ìfihàn 11:13 ni o tọ