Ìfihàn 11:2 BM

2 Má wulẹ̀ wọn àgbàlá Tẹmpili tí ó wà lóde, nítorí a ti fi fún àwọn alaigbagbọ. Wọn yóo gba ìlú mímọ́ fún oṣù mejilelogoji.

Ka pipe ipin Ìfihàn 11

Wo Ìfihàn 11:2 ni o tọ