Ìfihàn 12:17 BM

17 Inú wá bí Ẹranko Ewèlè yìí sí obinrin náà. Ó wá lọ gbógun ti àwọn ọmọ rẹ̀ yòókù, tí wọn ń pa àṣẹ Ọlọrun mọ́, tí wọn ń jẹ́rìí igbagbọ ninu Jesu.

Ka pipe ipin Ìfihàn 12

Wo Ìfihàn 12:17 ni o tọ