Ìfihàn 12:7 BM

7 Ogun wá bẹ́ sílẹ̀ ní ọ̀run. Mikaeli ati àwọn angẹli rẹ̀ ń bá Ẹranko Ewèlè náà jà. Ẹranko Ewèlè yìí ati àwọn angẹli rẹ̀ náà jà títí,

Ka pipe ipin Ìfihàn 12

Wo Ìfihàn 12:7 ni o tọ