Ìfihàn 13:15 BM

15 A fún un ní agbára láti fi èémí sinu ère ẹranko náà, kí ère ẹranko náà lè fọhùn, kí ó lè pa àwọn tí kò bá júbà ère ẹranko náà.

Ka pipe ipin Ìfihàn 13

Wo Ìfihàn 13:15 ni o tọ